Hunje gege bi obi e mahun ba omo soro lori ibalopo bi i?
Hunje eti e mo bo ya ibale omo shi wa lai laba won bi i?
Hunje eko omo yin lati ko ara re ni ijanu lori ibalopo bi i?
Hunje e jeki won mo iha ti asa ati isewa pelu awon esin wa
kosi bi i?
Hunje eso fun won pe oju kan lada ni lotona fun won lati je
atipe didi ida kotona rara?
Hunje ejiki won mo awon iwa ti oto ati eyi ti oye papajulo
lori ibalopo ati eyi ti ko tona rara lati she?
Ojushe wa ni lati ba awon omo wa soro lori ibalopo ati ohun ti
o ro mo.
Eje ki won naani e o o o ki won le mo pe ki i she ohun ye pere
rara o o o.
Ese te e teti simi.
Aku apero o o o.
E ma shalai fi ero o yin han ninu comments o.
Thank you for listening and watching!
We are new SUBSCRIBE! LIKE! SHARE!
Do feel free to comment your take on today's call for Akiyesi i
Aku eto o o o.