AA14:Àkiyesi i............She awon omo yi tabili yin ka

Hunje ehun jehun po pelu awon omo yin bi i? Eje ka ma jeun po pelu awon omo wa.

AA13:Akiyesi i......Ohun iso ro o wa a hun un un eyin lohun o o o !

Pele oni Ako oni Abo o o o.

Hunje eti e mo pe eyin lohun bi i?

Hunje e ti e fi erosi ke to so ohun kohun?

AA12:Akiyesi i..........Siso ejo o ati ese e nigbati o to nigbati o ye

Ojowo leti so ejo o pls ati ese thankyou gbe yin? She e ti e ma a so rara?

AA11:Akiyesi i........Oge grooming awon omo wa

She efi oge shishe ko awon omo yin bi i? Hunje e ti mo pe oge shishe fun awon omo wa ko ju:

AA10:Akiyesi i.......Eko ìlè ise ìlè she Pataki o

Hunje eti e fi eko ile komo bi i? Hunje e eti e fi ise ile komo bi i? Abi she ni e ma hun so pe haa omo ilu oyinbo ni i?

AA9:Akiyesi i......ewa ede wa siso o ka fi komo she patakii pupo o.

Hunje e hun so ede abinibi yin si awon omo yin bi i? Hunje won ti e gbo ede,le so ede yin?

AA 8:Akiyesi i........ikini

Hun je e hun ki awon omo yin karo  bi i? Hunje awon naa ki i yin bi i?

AA7:Akiyesi i........Oro ibalopo oye ki a ba awon omo wa so o o/3.

Hunje gege bi obi e mahun ba omo soro lori ibalopo bi i? 
Blogger Tips and TricksLatest Tips And TricksBlogger Tricks

Now Trending